Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 16:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si yan ninu awọn ọmọ Lefi lati ma jọsin niwaju apoti ẹri Oluwa, ati lati ṣe iranti, ati lati dupẹ, ati lati yìn Oluwa Ọlọrun Israeli:

Ka pipe ipin 1. Kro 16

Wo 1. Kro 16:4 ni o tọ