Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 15:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Ṣebaniah, ati Jehoṣafati, ati Netaneeli, ati Amasai, ati Sekariah, ati Benaiah, ati Elieseri, awọn alufa, li o nfun ipè niwaju apoti ẹri Ọlọrun: ati Obed-Edomu, ati Jehiah li awọn adena fun apoti ẹri na.

Ka pipe ipin 1. Kro 15

Wo 1. Kro 15:24 ni o tọ