Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 14:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni nwọn gòke lọ si Baal-perasimu; Dafidi si kọlù wọn nibẹ. Dafidi si wipe, Ọlọrun ti ti ọwọ mi yà lu awọn ọta mi bi yiya omi: nitorina ni nwọn ṣe npè ibẹ na ni Baal-perasimu.

Ka pipe ipin 1. Kro 14

Wo 1. Kro 14:11 ni o tọ