Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 13:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si gòke ati gbogbo Israeli si Baala, si Kirjat-jearimu, ti iṣe ti Juda, lati mu apoti ẹ̀ri Ọlọrun Oluwa gòke lati ibẹ wá, ti ngbe arin Kerubimu, nibiti a npe orukọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin 1. Kro 13

Wo 1. Kro 13:6 ni o tọ