Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 12:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ẹmi bà lé Amasai, ti iṣe olori awọn ọgbọn na, wipe, Tirẹ li awa, Dafidi, tirẹ li a si nṣe, iwọ ọmọ Jesse: alafia! alafia ni fun ọ! alafia si ni fun awọn oluranlọwọ rẹ; nitori Ọlọrun rẹ ni nràn ọ lọwọ. Dafidi si gbà wọn, o si fi wọn jẹ olori ẹgbẹ-ogun.

Ka pipe ipin 1. Kro 12

Wo 1. Kro 12:18 ni o tọ