Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 10:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Saulu wi fun ẹniti o ru ihamọra rẹ̀ pe, Fa idà rẹ yọ, ki o si fi gun mi, ki awọn alaikọla wọnyi ki o má ba wá fi mi ṣẹsin. Ṣugbọn ẹniti o ru ihamọra rẹ̀ kọ̀, nitori ẹ̀ru ba a gidigidi. Bẹ̃ni Saulu si mu idà, o si ṣubu le e.

Ka pipe ipin 1. Kro 10

Wo 1. Kro 10:4 ni o tọ