Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 10:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ara Filistia si lepa Saulu kikan, ati awọn ọmọ rẹ̀: awọn ara Filistia si pa Jonatani, ati Abinadabu, ati Melkiṣua, awọn ọmọ Saulu.

Ka pipe ipin 1. Kro 10

Wo 1. Kro 10:2 ni o tọ