Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 1:3-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Henoki, Metusela, Lameki,

4. Noa, Ṣemu, Hamu, ati Jafeti,

5. Awọn ọmọ Jafeti; Gomeri, ati Magogu, ati Madai, ati Jafani, ati Tubali, ati Meṣeki, ati Tirasi,

6. Ati awọn ọmọ Gomeri; Aṣkenasi, ati Rifati, ati Togarma.

7. Ati awọn ọmọ Jafani; Eliṣa, ati Tarṣiṣi, Kittimu, ati Dodanimu.

8. Awọn ọmọ Hamu; Kuṣi, ati Misraimu, Puti, ati Kenaani.

9. Ati awọn ọmọ Kuṣi; Ṣeba, ati Hafila, ati Sabta, ati Raama, ati Sabteka. Ati awọn ọmọ Raama; Ṣeba ati Dedani.

10. Kuṣi si bi Nimrodu: on bẹ̀rẹ si di alagbara li aiye.

11. Misraimu si bi Ludimu, ati Anamimu, ati Lehabimu, ati Naftuhimu,

12. Ati Patrusimu, ati Kasluhimu, (lọdọ ẹniti awọn ara Filistia ti wá,) ati Kaftorimu.

13. Kenaani si bi Sidoni akọbi rẹ̀, ati Heti,

14. Ati awọn ara Jebusi, ati awọn ara Amori, ati awọn ara Girgaṣi,

15. Ati awọn ara Hifi, ati awọn ara Arki, ati awọn ara Sini,

16. Ati awọn ara Arfadi, ati awọn ara Semari, ati awọn ara Hamati.

17. Awọn ọmọ Ṣemu; Elamu, ati Assuri, ati Arfaksadi, ati Ludi, ati Aramu, ati Usi, ati Huli, ati Geteri, ati Meṣeki.

18. Arfaksadi si bi Ṣela; Ṣela si bi Eberi.

19. Ati fun Eberi li a bi ọmọkunrin meji: orukọ ọkan ni Pelegi; nitori li ọjọ rẹ̀ li a pin aiye niya: orukọ arakunrin rẹ̀ si ni Joktani.

20. Joktani si bi Almodadi, ati Ṣelefi, ati Hasarmafeti, ati Jera,

21. Ati Hadoramu, ati Usali, ati Dikla,

22. Ati Ebali, ati Abimaeli, ati Ṣeba,

Ka pipe ipin 1. Kro 1