Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 1:10-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

10. Kuṣi si bi Nimrodu: on bẹ̀rẹ si di alagbara li aiye.

11. Misraimu si bi Ludimu, ati Anamimu, ati Lehabimu, ati Naftuhimu,

12. Ati Patrusimu, ati Kasluhimu, (lọdọ ẹniti awọn ara Filistia ti wá,) ati Kaftorimu.

13. Kenaani si bi Sidoni akọbi rẹ̀, ati Heti,

14. Ati awọn ara Jebusi, ati awọn ara Amori, ati awọn ara Girgaṣi,

15. Ati awọn ara Hifi, ati awọn ara Arki, ati awọn ara Sini,

16. Ati awọn ara Arfadi, ati awọn ara Semari, ati awọn ara Hamati.

17. Awọn ọmọ Ṣemu; Elamu, ati Assuri, ati Arfaksadi, ati Ludi, ati Aramu, ati Usi, ati Huli, ati Geteri, ati Meṣeki.

18. Arfaksadi si bi Ṣela; Ṣela si bi Eberi.

19. Ati fun Eberi li a bi ọmọkunrin meji: orukọ ọkan ni Pelegi; nitori li ọjọ rẹ̀ li a pin aiye niya: orukọ arakunrin rẹ̀ si ni Joktani.

20. Joktani si bi Almodadi, ati Ṣelefi, ati Hasarmafeti, ati Jera,

Ka pipe ipin 1. Kro 1