Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li emi o fi idi itẹ́ ijọba rẹ mulẹ lori Israeli titi lai, bi mo ti ṣe ileri fun Dafidi baba rẹ, wipe, Iwọ kì yio fẹ ọkunrin kan kù lori itẹ́ Israeli.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9

Wo 1. A. Ọba 9:5 ni o tọ