Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 9:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigba mẹta li ọdun ni Solomoni iru ẹbọ ọrẹ-sisun, ati ẹbọ-ọpẹ lori pẹpẹ ti o tẹ́ fun Oluwa, o si sun turari lori eyi ti mbẹ niwaju Oluwa. Bẹ̃li o pari ile na.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9

Wo 1. A. Ọba 9:25 ni o tọ