Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:58 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki o fa ọkàn wa si ọdọ ara rẹ̀, lati ma rin ninu gbogbo ọ̀na rẹ̀, ati lati pa ofin rẹ̀ mọ́, ati aṣẹ rẹ̀, ati idajọ rẹ̀, ti o ti paṣẹ fun awọn baba wa.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:58 ni o tọ