Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Solomoni ọba, ati gbogbo ijọ enia Israeli ti o pejọ si ọdọ rẹ̀ wà pẹlu rẹ̀ niwaju apoti-ẹri, nwọn nfi agutan ati malu ti a kò le mọ̀ iye, ti a kò le kà fun ọ̀pọlọpọ rubọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:5 ni o tọ