Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iyàn ba mu ni ilẹ, bi ajakalẹ-arùn ni, tabi ìrẹdanu, tabi bibu, tabi bi ẽṣu tabi bi kòkorò ti njẹrun ba wà; bi ọtá wọn ba dó tì wọn ni ilẹ ilu wọn; ajakalẹ-arùn gbogbo, arùn-ki-arun gbogbo.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:37 ni o tọ