Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a ba sé ọrun mọ, ti kò si òjo, nitoriti nwọn ti dẹṣẹ si ọ: bi nwọn ba gbadura si iha ibi yi, ti nwọn si jẹwọ orukọ rẹ, bi nwọn ba si yipada kuro ninu ẹ̀ṣẹ wọn, nigbati iwọ ba pọ́n wọn li oju.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:35 ni o tọ