Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si duro niwaju pẹpẹ Oluwa, loju gbogbo ijọ enia Israeli, o si nà ọwọ́ rẹ̀ mejeji soke ọrun:

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:22 ni o tọ