Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si mu ọ̀rọ rẹ̀ ṣẹ ti o ti sọ, emi si dide ni ipò Dafidi, baba mi, mo si joko lori itẹ́ Israeli, gẹgẹ bi Oluwa ti sọ, emi si kọ́ ile kan fun orukọ Oluwa, Ọlọrun Israeli.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:20 ni o tọ