Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 8:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun Dafidi baba mi pe, Bi o tijẹpe o wà li ọkàn rẹ lati kọ́ ile kan fun orukọ mi, iwọ ṣe rere ti o fi wà li ọkàn rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:18 ni o tọ