Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 7:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo iṣẹ ti Solomoni ọba ṣe fun ile Oluwa pari. Solomoni si mu gbogbo nkan ti Dafidi baba rẹ̀ ti yà si mimọ́ wá; fadaka, ati wura, ati ohun-elo, o si fi wọn sinu iṣura ile Oluwa.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7

Wo 1. A. Ọba 7:51 ni o tọ