Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 7:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O duro lori malu mejila, mẹta nwo iha ariwa, mẹta si nwo iwọ-õrun, mẹ̃ta si nwo gusu, mẹta si nwo ila-õrun; agbada nla na si joko lori wọn, gbogbo apa ẹhin wọn si mbẹ ninu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7

Wo 1. A. Ọba 7:25 ni o tọ