Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 7:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe agbada nla didà igbọnwọ mẹwa lati eti kan de ekeji: o ṣe birikiti, giga rẹ̀ si jẹ igbọnwọ marun: okùn ọgbọ̀n igbọnwọ li o si yi i kakiri.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7

Wo 1. A. Ọba 7:23 ni o tọ