Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 7:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbe awọn ọwọ̀n na ro ni iloro tempili: o si gbe ọwọ̀n ọ̀tun ró, o si pe orukọ rẹ̀ ni Jakini: o si gbe ọwọ̀n òsi ró, o si pe orukọ rẹ̀ ni Boasi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7

Wo 1. A. Ọba 7:21 ni o tọ