Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 5:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

HIRAMU, ọba Tire, si rán awọn iranṣẹ rẹ̀ si Solomoni; nitoriti o ti gbọ́ pe, a ti fi ororo yàn a li ọba ni ipò baba rẹ̀: nitori Hiramu ti fẹràn Dafidi li ọjọ rẹ̀ gbogbo.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 5

Wo 1. A. Ọba 5:1 ni o tọ