Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 4:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Juda ati Israeli ngbe li alafia, olukuluku labẹ àjara rẹ̀ ati labẹ igi ọpọtọ́ rẹ̀, lati Dani titi de Beerṣeba, ni gbogbo ọjọ Solomoni.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 4

Wo 1. A. Ọba 4:25 ni o tọ