Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 4:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si jọba lori gbogbo awọn ọba lati odò titi de ilẹ awọn ara Filistia, ati titi de eti ilẹ Egipti: nwọn nmu ọrẹ wá, nwọn si nsìn Solomoni ni gbogbo ọjọ aiye rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 4

Wo 1. A. Ọba 4:21 ni o tọ