Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, Oluwa Ọlọrun mi, iwọ ti fi iranṣẹ rẹ jẹ ọba ni ipo Dafidi, baba mi: ati emi, ọmọ kekere ni mi, emi kò si mọ̀ jijade ati wiwọle.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:7 ni o tọ