Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 3:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si wipe, Ọkan wipe, eyi li ọmọ mi ti o wà lãye, ati okú li ọmọ rẹ; ekeji si wipe, Bẹ̃kọ; ṣugbọn eyi okú li ọmọ rẹ, eyi alãye li ọmọ mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 3

Wo 1. A. Ọba 3:23 ni o tọ