Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 21:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun u pe, Nitoriti mo ba Naboti, ara Jesreeli sọ, mo si wi fun u pe, Fun mi ni ọgba-àjara rẹ fun owo; tabi bi o ba wù ọ, emi o fun ọ ni ọgba-àjara miran ni ipò rẹ̀: o si dahùn wipe, Emi kì o fun ọ ni ọgba-àjara mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 21

Wo 1. A. Ọba 21:6 ni o tọ