Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 21:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ri bi Ahabu ti rẹ̀ ara rẹ̀ silẹ niwaju mi? Nitori ti o rẹ̀ ara rẹ̀ silẹ niwaju mi, emi kì yio mu ibi na wá li ọjọ rẹ̀: li ọjọ ọmọ rẹ̀ li emi o mu ibi na wá sori ile rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 21

Wo 1. A. Ọba 21:29 ni o tọ