Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 20:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati emi ba rán awọn iranṣẹ mi si ọ ni iwòyi ọla, nigbana ni nwọn o wá ile rẹ wò, ati ile awọn iranṣẹ rẹ; yio si ṣe, ohunkohun ti o ba dara loju rẹ, on ni nwọn o fi si ọwọ́ wọn, nwọn o si mu u lọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:6 ni o tọ