Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 20:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o wi pe, Nitoriti iwọ kò gbà ohùn Oluwa gbọ́, kiyesi i, bi iwọ ba ti ọdọ mi kuro, kiniun yio pa ọ. Bi o si ti jade lọ lọdọ rẹ̀, kiniun kan ri i o si pa a.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:36 ni o tọ