Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 20:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni nwọn di aṣọ ọ̀fọ mọ ẹgbẹ wọn, nwọn si fi ijara yi ori wọn ka, nwọn si tọ̀ ọba Israeli wá, nwọn si wipe, Benhadadi, iranṣẹ rẹ, wipe, Emi bẹ ọ, jẹ ki ẹmi mi ki o yè. On si wipe, O mbẹ lãye sibẹ? arakunrin mi li on iṣe.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:32 ni o tọ