Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 20:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, woli kan tọ̀ Ahabu, ọba Israeli wá, wipe, Bayi li Oluwa wi, Iwọ ri gbogbo ọ̀pọlọpọ yi? kiyesi i, emi o fi wọn le ọ lọwọ loni; iwọ o si mọ̀ pe, Emi li Oluwa.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:13 ni o tọ