Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

BENHADADI, oba Siria si gbá gbogbo ogun rẹ̀ jọ: ọba mejilelọgbọn si mbẹ pẹlu rẹ̀ ati ẹṣin ati kẹkẹ́: o si gokè lọ, o si dóti Samaria, o ba a jagun.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:1 ni o tọ