Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 19:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi awọn malu silẹ o si sare tọ̀ Elijah lẹhin o si wipe, Emi bẹ̀ ọ, jẹ ki emi lọ ifi ẹnu kò baba ati iya mi li ẹnu, nigbana ni emi o tọ̀ ọ lẹhin. O si wi fun u pe, Lọ, pada, nitori kini mo fi ṣe ọ?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19

Wo 1. A. Ọba 19:20 ni o tọ