Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 19:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Jehu, ọmọ Nimṣi ni iwọ o fi ororo yàn li ọba lori Israeli: ati Eliṣa, ọmọ Ṣafati, ara Abel-Mehola ni iwọ o fi ororo yan ni woli ni ipò rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19

Wo 1. A. Ọba 19:16 ni o tọ