Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 19:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Ni jijowu emi ti njowu fun Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun: nitoriti awọn ọmọ Israeli ti kọ̀ majẹmu rẹ silẹ, nwọn ti wó awọn pẹpẹ rẹ lulẹ, nwọn si ti fi idà pa awọn woli rẹ: ati emi, ani emi nikanṣoṣo li o kù, nwọn si nwá ẹmi mi lati gba a kuro.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 19

Wo 1. A. Ọba 19:10 ni o tọ