Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu si wi fun Obadiah pe, Rin ilẹ lọ, si orisun omi gbogbo, ati si odò gbogbo: bọya awa le ri koriko lati gbà awọn ẹṣin ati awọn ibãka là, ki a má ba ṣòfo awọn ẹranko patapata.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:5 ni o tọ