Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, ni igba keje, o si wipe, Kiyesi i, awọsanmọ kekere kan dide lati inu okun, gẹgẹ bi ọwọ́ enia. On si wipe, Goke lọ, wi fun Ahabu pe, Di kẹkẹ́ rẹ, ki o si sọkalẹ, ki òjo ki o má ba da ọ duro.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:44 ni o tọ