Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, ni irubọ aṣalẹ, ni Elijah woli sunmọ tòsi, o si wipe, Oluwa Ọlọrun Abrahamu, Isaaki, ati Israeli, jẹ ki o di mimọ̀ loni pe, iwọ li Ọlọrun ni Israeli, emi si ni iranṣẹ rẹ, ati pe mo ṣe gbogbo nkan wọnyi nipa ọ̀rọ rẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:36 ni o tọ