Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi Oluwa Ọlọrun rẹ ti wà, kò si orilẹ-ède tabi ijọba kan, nibiti oluwa mi kò ranṣẹ de lati wò ọ: nigbati nwọn ba si wipe, Kò si; on a mu ki ijọba tabi orilẹ-ède na bura pe: awọn kò ri ọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:10 ni o tọ