Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 17:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elijah si mu ọmọde na, o si mu u sọkalẹ lati inu iyara-òke na wá sinu ile, o si fi i le iya rẹ̀ lọwọ: Elijah si wipe, Wò o, ọmọ rẹ yè.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 17

Wo 1. A. Ọba 17:23 ni o tọ