Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 14:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, kiyesi i, emi o mu ibi wá si ile Jeroboamu, emi o ke gbogbo ọdọmọkunrin kuro lọdọ Jeroboamu, ati ọmọ-ọdọ ati omnira ni Israeli, emi o si mu awọn ti o kù ni ile Jeroboamu kuro, gẹgẹ bi enia ti ikó igbẹ kuro, titi gbogbo rẹ̀ yio fi tan.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 14

Wo 1. A. Ọba 14:10 ni o tọ