Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si dahùn, o si wi fun enia Ọlọrun na pe, Tù Oluwa Ọlọrun rẹ loju nisisiyi, ki o si gbadura fun mi, ki a ba le tun mu ọwọ́ mi bọ̀ sipo fun mi. Enia Ọlọrun na si tù Ọlọrun loju, a si tun mu ọwọ́ ọba bọ̀ sipo fun u, o si dàbi o ti wà ri.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:6 ni o tọ