Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, lẹhin igbati o ti sinkú rẹ̀ tan, o si sọ fun awọn ọmọ rẹ̀ wipe, Nigbati mo ba kú, nigbana ni ki ẹ sinkú mi ni iboji ninu eyiti a sin enia Ọlọrun; ẹ tẹ́ egungun mi lẹba egungun rẹ̀:

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:31 ni o tọ