Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, awọn enia nkọja, nwọn ri pe, a gbe okú na sọ si oju ọ̀na, kiniun na si duro tì okú na: nwọn si wá, nwọn si sọ ọ ni ilu ti woli àgba na ngbe.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:25 ni o tọ