Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kigbe si enia Ọlọrun ti o ti Juda wá wipe, bayi li Oluwa wi: Niwọn bi iwọ ti ṣe aigbọran si ẹnu Oluwa, ti iwọ kò si pa aṣẹ na mọ ti Oluwa Ọlọrun rẹ pa fun ọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:21 ni o tọ