Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 13:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti a sọ fun mi nipa ọ̀rọ Oluwa pe, Iwọ kò gbọdọ jẹ onjẹ, iwọ kò si gbọdọ mu omi nibẹ, bẹ̃ni iwọ kò gbọdọ tun pada lọ nipa ọ̀na ti iwọ ba wá.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 13

Wo 1. A. Ọba 13:17 ni o tọ