Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 11:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Farao wi fun u pe, ṣugbọn kini iwọ ṣe alaini lọdọ mi, si kiyesi i, iwọ nwá ọ̀na lati lọ si ilu rẹ? O si wipe: Kò si nkan: ṣugbọn sa jẹ ki emi ki o lọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:22 ni o tọ