Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 11:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiki pe emi kì yio fà gbogbo ijọba na ya; emi o fi ẹyà kan fun ọmọ rẹ, nitori Dafidi iranṣẹ mi, ati nitori Jerusalemu ti mo ti yàn.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:13 ni o tọ